audio audioduration (s) 0.06 25.8 | transcription stringlengths 4 183 |
|---|---|
Lọ ṣíbẹ̀ ko lọ ṣèké fún mi lọ́làá nípa ohun tó ṣẹlẹ̀. | |
Wàá pa òwe rẹ ní ọ̀la | |
Àwọn Krìstẹ́nì ma ń jọ́sìn ní ṣọ́ọ̀ṣì ní gbogbo ọjọ́ ìsinmi | |
Ṣé o ti rí nǹkan oṣù rẹ bí? | |
Emi yoo ka diẹ sii nipa awọn igi moringa | |
Mo n fojú sónà sí níní ònà tuntun láti ma po kankéré | |
Ọ̀nà táwọn atukọ̀ òkun máa ń gbà bá ara wọn sọ̀rọ̀ ni pé wọ́n máa ń sọ̀rọ̀ | |
Báwo ló ṣe máa jẹun nínú yàrá lọ́la nígbà tí àwọn ọ̀rẹ́ẹ̀ rẹ máa jẹun ní pálọ̀? | |
Aṣọ nọọsi yóò jẹ́ ìtura fún wọn | |
Báwo ni wọ́n ń ṣe lè efo lọ́jà. | |
Rárá, olùkọ́ ni ó bá àwọn ọmọ ilé-ìwé sọ̀rọ̀ nípa ìbọ̀wọ̀. | |
Ṣe o ri bọọlu ni orí pápá? | |
Ẹ̀sìn Ábúráhámù jẹ́ ẹ̀sìn tó wá láti ẹ̀sìn pàtó kan, ta mọ̀ sí Ẹ̀sìn Judaism, Kìtẹ́ẹ́nì àti Islam. | |
Ọkùnrin náà ń fẹ́ dókítà rẹ̀ | |
Ọ̀pọ̀ dókítà ni yóò wọ súkúrọ́bù ní ilé-ìwòsàn. | |
Emi yoo ni ifẹ lati ṣe gige gigun ejika ṣugbọn ni ibanujẹ Emi ko ni irun gigun | |
Mo ti lo oògùn náà | |
Awọn awujọ iwaju le yipada kuro ni sisọpọ awọn ihuwasi kan pato bii ofofo pẹlu awọn obinrin nikan | |
Ìyá ọlá máa ń rán aṣọ ọlọ́pàá | |
Ọmọ ile-ikawe ṣe iranlọwọ fun awọn ọmọ ile-iwe ati awọn olukọ ni iraye si awọn orisun eto-ẹkọ | |
Bàbá Títí ní dandan kó ní tábìlì ègbé àga. | |
Bàtà jẹ́ ohun tí a ń wọ̀ sí ẹsẹ̀ láti fi dabobo ẹsẹ̀ | |
Rárá, ó ní òun kò ní wá pẹ̀lú ìgbá náà. | |
Taló f'òpin sí fífi owó ẹyọ ṣe óńka? | |
Ìyá mi yóò ra epo pupa ni ilé-ìtajà ńlá. | |
Má ṣe fi ìbọn bàbá rẹ̀ seré mọ́ láíláí . | |
Ìdènà ipanilaya le lo awọn ọgbọn ilọsiwaju ati awọn idasi. | |
Rárá, Shínà Peters ọ̀ ní ṣeré ní ibi ayẹyẹ náà ní ọ̀la | |
íyará ikáwe jelésímí, ni erò aworán kan. | |
Òǹkàwé akọ́ṣẹ́mọṣẹ́ ni ẹ̀gbọ́n mi | |
Ọ̀la ni àwọn awakọ̀ ojú omi náà wí pé àwọn yóò pa ẹja bọ̀ | |
Ilé ìwé ẹ̀kọ́ ní àwọn ohun èlò fún ẹ̀kọ́ kíkọ́. | |
Ìdí tó rọ̀ mọ́ abẹ́ dídá jẹ́ ti àṣà àti ẹ̀sìn | |
Kí ni ẹ fún Ejò náà jẹ? | |
Ààrẹ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà jẹ́ ọkùnrin | |
O yóò parí iṣẹ náà nípasẹ̀ lilo kọnputa náà | |
Lẹ́hinna, àwọn kùnkùn ń kó lọ ní àárín. | |
Ilé alájà akọkọ ní Nàìjíríà wa ni Badagry. | |
Ogbúdọ̀ lọ fún ìpolongo ọ̀la | |
Èrèlé jẹ́ oṣù kejì nínú oṣù tó ń bẹ nínú ọdún. | |
Kazeem fè ṣe ògún owó. | |
Olórí kíláàsì ni ó ń rí sí dídarí ìrírí ẹ̀kọ́ àwọn akẹ́kọ̀ọ́. | |
Ọmọ náà bẹ̀rẹ̀ sí ní rìn ní ọdún méjì. | |
Ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn olóṣèlú ni kò ṣe olóòótọ́. | |
Ẹwà ní mọ fẹ́ jẹ. | |
Awọn iru èrò bíí ResearchGate àti Academia ṣè iranlọwọ́ fún awọn oníwádì Naijíríà àti awọn ọjọ́gbọn láti ṣíṣẹ̀ papọ̀ àti pin imọ. | |
Mo jẹ kaṣú kí n tó sùn lánàá. | |
À ń lọ sí ilé ìjọsìn lọ́jọ́ ìsinmi | |
èmi àti Olùdarí agbègbè ọkọ òfurufú tí di ọrẹ | |
Ọ̀gẹ̀dẹ̀ tí mo kó sínú àpò tí tán. | |
Lọ́géèjì ní àwọn ẹrù ti àwọn a rin ìrìn àjò máa n gbé dání | |
Ṣé o rí ọ́fììsì akápò naa? | |
Mo fẹ́ máa kọ́ bí wọ́n ti ń se oúnjẹ ìgbàlódé lórí ìkànnì Youtube | |
Lọ́ ra ọṣẹ ìfọyín wá | |
Pe ọ̀gá ilé-ìwé báyìí! | |
Àwọn ilé-ìwòsàn ní ọjọ́ iwájú lè ṣètò àwọn ẹ̀ro ìmọ̀ síáyẹ́nsì fún ìlera pípé fún aláìsàn | |
Awọn ilẹ̀-ifọ̀wọpamọ míkrófáìnánsì ṣe atilẹ̀yin awọn iṣowo iwọn kẹkẹre ni Nàìjíríà. | |
Òróró nìkan ni a lè fi dín ẹyin | |
Emi yóò lo girètạ làti gé ésò kàbèeji yii. | |
Baba mi feran jijẹ ọbẹ Ewedu Soup pelu amala. | |
Ọkọ ayọkẹlẹ máa ṣiṣẹ lati ará títàn ìṣìnà. | |
Yóò fọ́ ìgò kejì lórí ìyàwó rẹ̀ | |
ràrá mi'o ní jé ewé Moringa. | |
Rárá, mi ò san owó ẹgbẹ́. | |
Máa lọ ewé ólífì fún ẹ̀jẹ̀ ríru ìyá àgbà. | |
Bẹ́ẹ̀ ni, aṣọ́nà náà yẹ báágì rẹ̀ wò. | |
Ayò kò parí ẹ̀kọ́ rẹ̀ ninu èdè Gẹ̀ẹ́sì àti lítíréṣọ̀ rẹ̀. | |
Ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ènìyàn ni ó ń parí ẹ̀kọ́ wọn sí ilé ẹ̀kọ́ gírámà. | |
Ǹjẹ́ Bísí àti àwọn ọ̀rẹ́ rẹ̀ ni àwọn ọlọ́pàá kó lánàá? | |
Ó fẹ́ràn láti máa ṣiṣẹ́ lórí Instagram. | |
Dákẹ́! Ìwọ lo gbé dòdò náà. | |
ọ̀ọ́dúnrún ó lé mẹ́rin jẹ́ onka púráìmù | |
Ní ọjó ìkokanlélógún ní oṣù agemo | |
Rántí ọmọ ẹni tí ìwọ n se | |
Àwọn ọ̀dọ́mọdé wọ̀nyí ń fẹ́ra wọn lórí ẹ̀rọ ayélujára. | |
Lu sọ́jà tó rí mi fín lálùbami lọ́la. | |
Wọ́n wọ ọkọ̀-òfurufú lọ sí Àbújá lánàá. | |
Bisikíìtì kò wọ́pọ̀ nílẹ̀ Yorùbá láyé àtijọ́ | |
Gbogbo táyà náà kún fún eruku. | |
Ó kígbe, 'Máa sáré lọ! | |
oúnjẹ àyànfẹ rẹ ni eko áti àkàrà . | |
Bẹ́ẹ̀ni, mo mọ ẹni tí ó ń kun jú rẹ | |
Àwọn ìjọba máa ń sọ̀rọ̀ lòdì sí ìwà ipá ètò ìdìbò ní gbogbo ìgbà. | |
ó ń máa ń lọ sí ilé àwọn àkàndá dáadáa | |
Bàbá yóò ra kẹrosíìnì láti se oúnjẹ | |
Ìyá rẹ̀ gba owó láti ilé ìfowópamọ́ láti kọ́ ilé | |
Símẹ́ǹtì yìí yóò lè gan-an tí òjò bá paá. | |
Àwọn akẹ́kọ̀ọ́ wa ti lọ fún ìdíje badminton. | |
Irú yen máa bàjẹ́ kí o tó di ọ̀la. | |
Mi ò tíì rí ibi tí ọkọ ofurufu ti fa ìlà sójú Òfurufú rí. | |
Bawo ni awọn oṣere fiimu ṣe aṣeyọri ilosiwaju ati ṣiṣatunṣe ni awọn iṣelọpọ imusin? | |
Kọ́lá máa jáwé amáraró lọ́la. | |
There is an express way in Ilé Ife | |
Ìyá mi nífẹ̀ẹ́ sí ìjọ tuntun náà. | |
Àwọn akẹ́kọ̀ọ́ kọṣẹ́ sínú ìwé wọn. | |
Ibo ni Abidjan wa? | |
Iya mi jẹ iya agba ni bayi | |
Ní àná, mo lọ sí ibùdó ìṣeré láti lọ pàdé olólùfẹ́ mi | |
Ojúbọ jẹ́ ibi mímọ́ tí ó wà fún òrìṣà tàbí ẹ̀mí kan pàtó. | |
Erin kò ní pẹ́ di ẹranko ilé ni ọdún di ẹ síí isinyi |
End of preview. Expand in Data Studio
README.md exists but content is empty.
- Downloads last month
- 39